Africa / Nigeria

Akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga, Olamide, kú lẹ́yìn tí wọ́n fipá mú un kọ ìdánwò nígbà tó ń ṣàìsàn; Akẹ́kọ̀ọ́ pàdánù ẹ̀mí ní Yábà lẹ́yìn tó kẹ́nu ìfẹ́ sí ọ̀rẹ́bìnrin aṣáájú ẹgbẹ́ òkùnkùn

Akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga, Olamide, kú lẹ́yìn tí wọ́n fipá mú un kọ ìdánwò nígbà tó ń ṣàìsàn; Akẹ́kọ̀ọ́ pàdánù ẹ̀mí ní Yábà lẹ́yìn tó kẹ́nu ìfẹ́ sí ọ̀rẹ́bìnrin aṣáájú ẹgbẹ́ òkùnkùn

Lórí ètò Ìwòyé lónìí: Akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga, Olamide, kú lẹ́yìn tí wọ́n fipá mú un kọ ìdánwò nígbà tó ń ṣàìsàn. Deborah, ọmọ ọdún méjìlélógún, kú nígbà tó ń ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ ní ilé-ìtura. Akẹ́kọ̀ọ́ pàdánù ẹ̀mí ní Yábà lẹ́yìn tó kẹ́nu ìfẹ́ sí ọ̀rẹ́bìnrin aṣáájú ẹgbẹ́ òkùnkùn

Share this story WhatsApp Facebook X
Read the full report from Vanguard
Read the full story

Comments 0

No comments yet. Start the conversation.

Africa · Vanguard · 1 day ago

How judo moulded IGP Disu into a leader

…pledges to unite stakeholders, revive grassroots development ,Nigeria’s international presence By Evelyn Usman Long before he became the Inspector-General of Police, Olatunji Disu had learnt some of the lessons that wou...

Loading the next story…