Africa / Nigeria

Ìwòye: Akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́rin Yunifásítì Nsúkà kú lẹ́yìn tí wọ́n jẹ oògùn olóró àti ọtí níbi ayẹyẹ ìparí ẹ̀kọ́; Ọmọ pa bàbá rẹ̀ ní Ẹdó lẹ́yìn tí pásítọ̀ jíṣẹ́ fún un pé bàbá rẹ̀ ló fa ìṣòro tó bá a

Ìwòye: Akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́rin Yunifásítì Nsúkà kú lẹ́yìn tí wọ́n jẹ oògùn olóró àti ọtí níbi ayẹyẹ ìparí ẹ̀kọ́; Ọmọ pa bàbá rẹ̀ ní Ẹdó lẹ́yìn tí pásítọ̀ jíṣẹ́ fún un pé bàbá rẹ̀ ló fa ìṣòro tó bá a

Home » Top Podcasts » Ìwòye: Akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́rin Yunifásítì Nsúkà kú lẹ́yìn tí wọ́n jẹ oògùn olóró àti ọtí níbi ayẹyẹ ìparí ẹ̀kọ́; Ọmọ pa bàbá rẹ̀ ní Ẹdó lẹ́yìn tí pásítọ̀ jíṣẹ́ fún un pé bàbá rẹ̀ ló fa ìṣòro tó bá a

Ìwòye: Akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́rin Yunifásítì Nsúkà kú lẹ́yìn tí wọ́n jẹ oògùn olóró àti ọtí níbi ayẹyẹ ìparí ẹ̀kọ́; Ọmọ pa bàbá rẹ̀ ní Ẹdó lẹ́yìn tí pásítọ̀ jíṣẹ́ fún un pé bàbá rẹ̀ ló fa ìṣòro tó bá a

Lónìí lórí ètò Ìwòyé:

Akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́rin Yunifásítì Nsúkà kú lẹ́yìn tí wọ́n jẹ oògùn olóró àti ọtí níbi ayẹyẹ ìparí ẹ̀kọ́.

Ọmọ pa bàbá rẹ̀ ní Ẹdó lẹ́yìn tí pásítọ̀ jíṣẹ́ fún un pé bàbá rẹ̀ ló fa ìṣòro tó bá a.

Àjọ LASTMA gba arìnrìn-àjò mẹ́tàdínlógún là nígbà tí ọkọ̀ akérò onígáàsì jóná ní Èkó.

Share this story WhatsApp Facebook X
Originally published by Vanguard
View on Vanguard

Comments 0

No comments yet. Start the conversation.

Loading the next story…