Africa / Nigeria

Ìwòye: Ní Ẹdó, ayálégbé fọ́ orí onílé nígbà tí àríyànjiyàn ṣẹlẹ̀ lórí owó ilé; Ní Òǹdó, wọ́n rí òkú oníṣòwò kan lẹ́yìn tí ó ya fídíò láti kéde pé òun fẹ́ gba ẹ̀mí ara rẹ̀

Ìwòye: Ní Ẹdó, ayálégbé fọ́ orí onílé nígbà tí àríyànjiyàn ṣẹlẹ̀ lórí owó ilé; Ní Òǹdó, wọ́n rí òkú oníṣòwò kan lẹ́yìn tí ó ya fídíò láti kéde pé òun fẹ́ gba ẹ̀mí ara rẹ̀

Home » Top Podcasts » Ìwòye: Ní Ẹdó, ayálégbé fọ́ orí onílé nígbà tí àríyànjiyàn ṣẹlẹ̀ lórí owó ilé; Ní Òǹdó, wọ́n rí òkú oníṣòwò kan lẹ́yìn tí ó ya fídíò láti kéde pé òun fẹ́ gba ẹ̀mí ara rẹ̀

Ìwòye: Ní Ẹdó, ayálégbé fọ́ orí onílé nígbà tí àríyànjiyàn ṣẹlẹ̀ lórí owó ilé; Ní Òǹdó, wọ́n rí òkú oníṣòwò kan lẹ́yìn tí ó ya fídíò láti kéde pé òun fẹ́ gba ẹ̀mí ara rẹ̀

Lónìí lórí ètò Ìwòyé:

Ní Ẹdó, ayálégbé fọ́ orí onílé nígbà tí àríyànjiyàn ṣẹlẹ̀ lórí owó ilé.

Ní ìpínlẹ̀ Òǹdó, wọ́n rí òkú oníṣòwò kan lẹ́yìn tí ó ya fídíò láti kéde pé òun fẹ́ gba ẹ̀mí ara rẹ̀.

Àwọn ará ìlú mú onípọ̀nmọ́ kan nítorí àyíká rẹ̀ tí kò mọ́ tónítóní.

Share this story WhatsApp Facebook X
Originally published by Vanguard
View on Vanguard

Comments 0

No comments yet. Start the conversation.

Loading the next story…