Akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga, Olamide, kú lẹ́yìn tí wọ́n fipá mú un kọ ìdánwò nígbà tó ń ṣàìsàn; Akẹ́kọ̀ọ́ pàdánù ẹ̀mí ní Yábà lẹ́yìn tó kẹ́nu ìfẹ́ sí ọ̀rẹ́bìnrin aṣáájú ẹgbẹ́ òkùnkùn
Lórí ètò Ìwòyé lónìí: Akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga, Olamide, kú lẹ́yìn tí wọ́n fipá mú un kọ ìdánwò nígbà tó ń ṣàìsàn. Deborah, ọmọ ọdún méjìlélógún, kú nígbà tó ń ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ ní ilé-ìtura. Ak...
