Ìwòye: Ní Ẹdó, ayálégbé fọ́ orí onílé nígbà tí àríyànjiyàn ṣẹlẹ̀ lórí owó ilé; Ní Òǹdó, wọ́n rí òkú oníṣòwò kan lẹ́yìn tí ó ya fídíò láti kéde pé òun fẹ́ gba ẹ̀mí ara rẹ̀
Lónìí lórí ètò Ìwòyé: Ní Ẹdó, ayálégbé fọ́ orí onílé nígbà tí àríyànjiyàn ṣẹlẹ̀ lórí owó ilé. Ní ìpínlẹ̀ Òǹdó, wọ́n rí òkú oníṣòwò kan lẹ́yìn tí ó ya fídíò láti kéde pé òun fẹ́ gba ẹ̀mí ara rẹ̀. Àwọn ará ìlú mú onípọ̀nmọ...
